Wolfgang Pauli

Wolfgang Ernst Pauli (April 25, 1900 – December 15, 1958) je ara orile-ede Ostria to je onimo fisiyiki oniriro ati ikan ninu awon asiwaju ninu fisiyiki ayosere. Ni odun 1945, leyin ti Albert Einstein ti filoruko re sile, o gba Ebun Nobel ninu Fisiyiki fun "afikun to se koko nipa iwari ofin tuntun Adaba re, opo iyasoto tabi opo Pauli," to jemo iro yiyi, to wa labe idimule elo ati gbogbo Kemistri.


From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Tubidy